Àwọn ibeere ti won saba maa n beere
A mọ pé yíyàn nípa ìlera ìbímọ lè dà bí ẹni pé ó nira, ó sì ṣeé ṣe kó dà bíi pé ò ní ìbéèrè púpọ. Láti ran ẹ lọwọ kí o ní ìmọ tó péye àti ìgboyà, a ti kó ìdáhùn sí díẹ lára àwọn ìbéèrè tí a mo pe àwọn eyan sábà máa ń béèrè nípa àwọn iṣẹ wa, nípa àwọn ọnà iṣẹyun tó dájú pé ó ní ààbò, àti nípa àwọn àṣàyàn ìlera ìbímọ.
Tí ìtàn náà tí o ń wá kò bá wà níbí, ẹ má ṣe ṣiyèméjì láti kan sí ẹgbẹ wa fún ìtónisọnà aládàáni àti ìrànlọwọ tó dá lórí ìpamọ.
Ìbánisọrọ àti Atilẹyìn
Gba àtìlẹyìn àti ìmọràn nípa ìṣẹyún
A pèsè àlàyé tó dá lórí ẹrí lórí ìṣẹyún aláìléwu. Iṣẹ ìmọràn ọfẹ wa wà ní ààbò, ìkọkọ, ìrọrùn, àti láìsí ìdájọ. A n duro de ifiranṣẹ rẹ!