Ètò Ìmúlò Ohun Àfipamọ́

TA NI WÁ ÀTI PÉ BAWO NI IBI ÌPAMỌ́ WÁ SE TÓ:

Safe2choose (Àwa tàbí ilẹ iṣẹ wa) je ilé isẹ to ni ètò ayélujára àti èrò ayarabiasa lati mu ki awọn ènìyàn kakiri ayé ni ẹ̀kọ́ imọ to péye lori bi ase le lo òògùn oyún ṣíṣẹ́, tó sì má jé kí wọn ni òògùn oyún ṣíṣẹ́ ni gba kugba ti wọn ba fẹ́ (sístẹ̀mù wa). Awọn ètò yi gba àmì ìdámò oni kálukú (PII) nípa ẹni tí lo, ati pẹlu awọn oṣiṣẹ ile iṣẹ, awọn oṣiṣẹ ti sise lati ile, ati tàwọn ti wa iṣẹ (Oṣiṣẹ). Ètò Ìmúlò Ohun Àfipamọ́ ma so nipa iru awon ida ni mo ti a gba àti ẹtọ àwọn tí lo wọn awọn idanimọ yìí. Nigbati a ba se ètò ìṣàkóso lori àwọn sistemu, awọn oṣiṣẹ ita yo fún yi ni awọn eto miran lati le je ki lílo rẹ lọ dáadáa.

A dá Ètò Ìmúlò Ohun Àfipamọ́ lati lè dáàbò bo Ìdánimọ̀ àwọn tí n lo.

ÌYÍPADÀ SÍ ÈTÒ ÌMÚLÒ OHUN ÀFIPAMỌ́ ATI ÀWỌN OHUN MÍRÀN TÍ A FI KUN.

A ní ètò lati se àtúnṣe sí ètò ìmúlò ohun àfipamọ́ yí ni ọjọ iwájú. A ò ní fi tó àwọn oníbárà wa ni eti ti atunṣe ohun kò bá ni mu ìpalára wà fún ètò ipamọ wọn – bi se se àtúnṣe lati mu ki ètò ìmúlò ohun àfipamọ́ yi tun dára si, tàbí ti tun awọn ọrọ ti a ko ko dada tẹ́lẹ̀ se, tàbí ṣíṣe àfikún ọrọ. Fún àwọn àtúnṣe tí ọ yẹ ki awon olubara wa mo, a ma fi atejise ránṣẹ́ sí wọn lórí ẹrọ ímeèlì wọn. Ti a ko ba ni ero ímeèlì awon oníbárà kan tabi meji, kò ni sí bí a ṣe ma fi atejise ranṣẹ sí wọn ti a ba se àwọn àtúnṣe won yi. A lè ṣe awọn àfikún tabi àtúnṣe yi ni pa dídá eto ayelujara miran tabi ibaraẹnisọrọ.
A lè fi àtúnṣe sí ètò ìmúlò ohun àfipamọ́ yi sí orí ètò ayélujára wa tàbí ki a fi ìwé ohùn se atejise sí ọ.

ÀWỌN IJAPỌ̀ SÍ AYÉ AYÉLUJÁRA TI ẸNÌ KẸTA.

ètò ìmúlò ohun àfipamọ́ wa kò ni ajọṣepọ kan kan pẹ̀lú àwọn àyè ayélujára ti ẹni kẹta lati sístẹ̀mù wa. A ọ ni ibamu sí lilọ, ayẹwo, tàbí ètò ìmúlò ohun àfipamọ́ iru aye ayelujara ẹni kẹta bẹ. Awọn eto ti ọ ba wa lori iru aye ayélujára owun ma wa lábé àbòètò ìmúlò ohun àfipamọ́, ọrọ ati eto ibi ipamọ ti ayé ayélujára yẹn. A ma gba e ni ìyànjú lati ri pe ọ ka won.

ÀWỌN OHUN ÌDÁNIMỌ̀ TÍ A MA GBÀ

Nínú ètò ìmúlò ohun àfipamọ́ wa, gbogbo àwọn ọrọ idanimọ ti a ma gbà ni a ma pe ni PII. A ma ko àwọn idanimọ yi jo lati odo gbongbo àwọn oníbárà wa, tí yíò fi iru oníbárà ti ọ ba je hàn. Àwọn ọrọ ohun ni:

  • Orúkọ
  • Ímeèlì adiresi
  • Nọmbà ìpè fóònù alágbèéká
  • Adirẹ̀sì ayé ayélujára, ẹ̀rọ ayarabiasa, àti èdè
  • Ibi ibùgbé
  • Àkókò
  • Èdè tí ẹ ń lò
  • Ọjọ́ orí, akọ tàbí abo, àwòrán, àti àwọn ohùn míràn ti oníbárà ba ni láti jẹ ká mọ.
  • Àwọn ohùn ti ọ yẹ kí oníbárà sọ nípa ètò ìlera rẹ, oyún tàbí àwọn ìdènà ti wọn ni, idi ti wọn fi ba sístẹ̀mù wa ni gbólóhùn, ati ọrọ lori bi wọn se le ri ìtọ́jú to péye gbà lati ile ìwòsàn ìjọba.
  • Ìdánimọ̀ iṣẹ àti àwọn àlàyé nípa ibi isẹ oni tọ̀hún
  • Àwọn ẹri tàbí igbelewon ti a fún sistemu.

BI A SE N GBA ÀLÀYÉ NÍPA RẸ.

A má gba àyè ki a to gba PII. Nípa ibaraenisoro pẹlú sístẹ̀mù, àwọn onibara wa ni lati fun wa ni ayé ni ibamu pẹlú (1) àwọn òfin ètò ìmúlò ohun àfipamọ́ wa ati (2) fún àkójọ, lilọ ati ìdídá dúró àwọn àlàyé ti e ti fún wa wọ̀nyí àti èyí ti sístẹ̀mù gbà fún lílò ọna ẹrọ.

Ní ọ̀nà míràn ẹ̀wẹ̀, nígbàkúùgbà ti onibara ba ni Ìbánisọ̀rọ̀ pẹlú sístẹ̀mù, o ma gbà PII lati owo one ẹrọ ti onibara ba lo ti yi ọ sí gbà PII ti onibara ba fún ni àsìkò Ìbánisọ̀rọ̀ pẹlú sístẹ̀mù.

A lè lo èyíkéyìí nínú àwọn ọ̀nà láti gba àlàyé nípa ara ẹni

  • Kí onibara fún ni láì fi pa mu wọn.
  • Nípa tí onibara bá ní ibaraẹnisọrọ pẹlú sístẹ̀mù tàbí àwọn aye ayélujára ti ẹni kẹta tàbí àwọn òṣìṣẹ́ ìta.
  • Ibanisoro pẹlu awọn onibara

Gbogbo ìgbà ni a má wa ọna ti ọ sunwọn ti ọ sí ṣe dáradára láti se àkójọpọ̀ PII.Tí abárí àwọnọ̀nà miran, a ó se àtúnṣe lori àwọn òfin ètò ìmúlò ohun àfipamọ́

BÍ A ṢE LÈ LO ÀWỌN ÀLÀYÉ NÍPA ARA ẸNI:

A ma lo àwọn PII ti a gba ni àwọn ọ̀nà báyìí:

  • A ma lo àwọn PII ti a gba ni àwọn ọ̀nà báyìí
  • Láti ba e ni Ìbánisọ̀rọ̀ bi ọnibara wa àmọ́ ti a ọ ni fi òpin sí fífún yin ni àwọn àlàyé to ọ ṣe pàtàkì ati ṣe ètò nípa ẹyà ara ibi.
  • Ṣíṣe àtìpó PII ki a ba le se àtúnṣe lori iṣẹ, ọja ati àwọn ohun ẹyẹ ti a fún yín àti/tàbí sọ fún yi ti ọ jẹ mọ àwọn àtúnṣe pàtàkì fún àwọn oníbara wa àti àwọn ìyókù
  • Ṣíṣe àwọn ise ìṣàkóso fún sístẹ̀mù ati/tàbí nipa sise iṣẹ ilé iṣẹ
  • Ṣíṣe ìwádìí fún ati/tàbí ilẹ iṣẹ
  • Fún àwọn ohun ẹ̀kọ́ ori ayélujára, a má ṣètò pẹlú àwọn ile iṣẹ miran, a má fún àwọn ile iṣẹ yi ni àwọn PII ti a gba láti ọ̀dọ̀ àwọn onibara wa ti ọ ko pa nínú awọn ẹkọ ori ayélujára yìí
  • Ṣíṣe iṣẹ wíwá owó, èyí ti ọ le ni fifi awọn àkójọpọ̀ àwọn PII fun àwọn ènìyàn ti ọ ba wù lati ran ile iṣẹ lowo.
  • Fifi PII fún àwọn agbófinró, ati àwọn ile iṣẹ ìjọba tàbí òṣìṣẹ́ won, àwọn oṣiṣẹ kẹta bi ofin ti fi lele, tàbí iwe láti ile ẹjọ́ tàbí àwọn ìdájọ́ ti wọn ba fún ilẹ iṣẹ wa.

A máa gbé ìgbésẹ̀ to ni túmọ̀ to si leto lábé òfin lati lè yẹra fún fifi tipátipá tu PII lati odo àwọn oṣiṣẹ ìjọba kankan tàbí ẹni kẹta tọ ọ ba ni ànfàní sí. Nigba miran, awọn oṣiṣẹ ijoba ati/tabi eni-keta le ni aṣẹ labẹ ofin lati je ki iru ile iṣẹ wa ti awọn PII, ni iru àwọn ìgbà ba yìí, ọ di dandan ki a se bẹ

Irú àwọn PII ti àwọn oṣiṣẹ bi eni keta ba gba ati/tabi fi pamo nípa si ṣiṣe sinu sístẹ̀mù, awa ko ni ipa lori lilọ ati/tàbí ipamọ iru PII yen.

Bi a ṣe ṣàlàyé ni apá ètò, àṣírí ibi ipamo ti a pe àkọlé rẹ ní “ÈTÒ RẸ LORI ÀLÀYÉ ÌDÁNIMỌ̀ RẸ”, ọ ni ẹtọ lati se bó bá ṣe wún ọ pẹlu PII gege bi a se salaye ni apa yen.

ÀWỌN ẸTỌ Ẹ LÁTI WỌ, ṢE ÀTÚNṢE, ÌDARÍ ÀTI YÍYỌ KÚRÒ ÀWỌN ÀLÀYÉ ÌDÁNIMỌ̀ RẸ

Àwọn ètò oníbárà wa nipa PII ni àwọn wọn yìí —

  • Nini àyè àti gigba ida iwe PII tire
  • Nini ìmọ nípa bí a ṣe lè gbà PII and bi a se lè lòó
  • Síṣe àtúnṣe tabi pi pa PII wọn rẹ.
  • Síṣe àtúnṣe ti ọ péye bi a se lè lo PII wọn

Lati lè lo agbára lori awọn eto yi, oníbárà ni lati pèsè ímeèlì adiresi ti ọ kun oju osunwon ati lati tẹle awọn ilana ti a ti fi sí isale ni bi apa eto asiri ibi ipamo ti a pe àkọlé rẹ ní “BI Ẹ SE LE BA WA SỌ̀RỌ̀ PẸ̀LÚ AWỌN IBẸRẸ, AFIKUN TABI AWON ORO YIN”. Ti oníbárà kan ko ba fún wa ni ímeèlì adiresi to kun oju osunwon, a wa ko ni ni afani lati lè bá iru eni bẹ soro: eyi sí fa idena sí (1) fifi ate ranṣẹ sí wọn ni pa àwọn àtúnṣe ti a se sí eto ibi ipamọ ati awọn ohun tó lè su yọ nipa PII won (2) ati ki a le se ayẹwo nipa idanimo won ki a ba le je ki won se eto won bo se tọ àti bí o se ye, se àtúnṣe, wa ni ipa won tabi parẹ PII won rẹ.

ÒFIN ÈTÒ ÌMÚLÒ OHUN ÀFIPAMỌ́ ÀTI IṢẸ́ ILÉ IṢẸ WA:

Àwa kì í gba idanimo àwọn ènìyàn lati omodun mẹtala sí ìsàlẹ̀. Nigba ti sístẹ̀mù wa ki se fún àwọn ọmọdé , ti a ko si se iwadi lẹkunrẹrẹ nipa ọjọ ori àwọn oníbárà wa, a le se sí gbà PII ti omode ti ọ ba lo sístẹ̀mù wa. O se de bi or awon oníbárà wa ma fi PII awọn eniyan ti ojo ori won jẹ́ ọmọ ọdún metala, ti ile iṣẹ waa yìo sì tọjú iru PII wa gẹgẹ bẹ ètò ìmúlò ohun àfipamọ́, wa. Ti a ba mọmọ ni ibanisoro pẹlu ọmọ ọdún mẹtala, a o ni ki iru eniyan bẹ gba ayé lodo agbalagba ki won to le bá sístẹ̀mù soro.

ÌDÁBÒBÒ ÀWỌN ÀLÀYÉ ÀTI ÌDÁDÚRÓ IBI IPAMỌ ATI IṢẸ SÍ:

Láti dabobo PII rẹ lọwọ olè àti ewu, ọ gbọdọ ṣe àwọn igbesẹ iwọnyi;

Ètò ẹkọ́ ìmúlò ohun àfipamọ́ yìí: A má da àwọn oṣiṣẹ wa, awọn alabaṣiṣẹpọ ati awọn eni kẹta ti fún wa ni iranwo wo nipa awọn ètò ìmúlò ohun àfipamọ́ ti, ti a sì má ke je won mo bi ojuse won ọ ṣe tọ ninu ji jeki awon ti ọ lẹtọ láti ni tabi lo PII ni ni ikawọ́ wọn.

Ìlọsíwájú Idáàbò: Àwọn ojúṣe wa láti jẹ ki Ìlọsíwájú dé bá àbọ̀ PII jẹyọ nínú ipa ti a ko lọwọlọwọ. A ti ṣe oríṣìíríṣìí àwọn àbọ̀ láti ma le jẹ ki àwọn ti ọ lẹtọ di PII ni ayé sì tàbí ki won lo. Ti a ba parí àwọn àtúnṣe lori àbọ̀, a ọ pèsè àkótán isẹ lori àwọn àtúnṣe ti a ti ṣe lori ètò ìmúlò ohun àfipamọ́. É ni ànfàní lati kan sí wa nigba ku gba lori àwọn nkan wọ̀nyí.

Dídá àwọn àlàyé sí ibi ipamọ – Iṣẹ wa ni lati pa PII rẹ lẹyìn ọdún kan ti a ba ti n lo. Àmọ́, ti a ba lo nipa bi sistemu wa se n sise, igba ti a ba da yi ki to lati se oun ti a fe. Ọ pọn dandan ki é sakiyesi pe, dídá ẹto ibi ipamọ yi sí kó jẹ mọ PII ti àwọn òṣìṣẹ́ ẹni kẹta ti n ba ni ṣẹṣẹ ba ko jọ tàbí gba.

Sise ìsekóòdù àwọn àlàyé sí ibi ipamọ: A má fẹ ayẹwo bi isekoodu àwọn PII ti a gba ba se nipọn sí, a sì má je kí sístẹ̀mù wa se ayewo lati ri wipe Isekoodu ibi ipamọ ti a gba wa ni ìsimi. Lowolowo bayii, a o ti ma lo awon ilana yi ni . Amo, isekoodu àwọn PII ko sí ní akawo to awọn oṣiṣẹ kẹta

Àwọn Òṣìṣẹ́ Kẹta ti fún wa ni isé: Fún àwọn òṣìṣẹ́ keta, a o ti ṣe ayẹwo fún wọn láti lè le mo bi iṣẹ abo won se sise su. Irú àwọn ayẹwo báyìí wọn pò ti wọn sì jẹ àsìkò fún iru àwọn ènìyàn bi ile iṣẹ wa; ati papa àwọn oṣiṣẹ kẹta ti fún wa ni isé ko gba irú àwọn ayẹwo báyìí láti wáyé

“MA ṢE TOPI PIN” ÈTÒ ÀFIHÀN:

Àwa kì í topi pin ènìyàn nípasẹ̀ ayé ayélujára ti ènìyàn kẹta lati se ìpolówó. Nítorí náà, àwa ko ni dáhùn sí ẹrọ itopinpin (DNT)

BÍ Ẹ SE LE BÁ WA SỌ̀RỌ̀ LÓRÍ ÀWỌN ÌBÉÈRÈ, IDASI TÀBÍ ÀWỌN OHUN TI E FẸ́:

Láti kàn sí wa fún ẹ̀bẹ̀, èsì tàbí ìbéèrè, ẹ jọ̀wọ́ ẹ kàn sí wa ní privacy@safe2choose.org. Kí á tó fún ọ ní èsì PII tàbí ṣe àyípadà sí PII. A ó lo email àdírẹsì lórí fáìlì láti ṣe wá ìdí ẹni tó ń ṣe ẹ̀bẹ̀. Ìpamọ́ rẹ jẹ wá lógún.

Bí a se sọ síwájú, tí o ko ba fún wa ní ímeèlì adiresi ti o yanjú ni gba ti o ba kókó ba wa sọ̀rọ̀, tàbí nígbà tí o fún wa ni PII, àwa kò ni le ṣe ìwádìí tó péye lori ẹni náà ti èyí yíò sì fa ìdènà lati jẹ́ ki a gba ki irú ẹni bẹ se ètò lori PII tí o ba wa ni àrọ́wọ́tó wa.

Ọ̀RỌ̀ TÍ Ó PARÍ:

Ètò àṣírí ibi ìpamọ́ yìí jẹ èyí ti a se àtúnṣe rẹ ni oṣù keje, odun 2024. A o sì tún ṣe àtúnṣe sí ètò àṣírí ibi ìpamọ́ yi ni ekan láàrin oṣù méjìlá.