Ìṣẹ́yùn Pẹ̀lú Àwọn Òògùn: Aláàbò, Tó Múnádóko, Tó Sí Ní Àṣírí
Ìṣẹ́yún oníṣègùn ni a sábà mọ̀ sí ìṣẹ́yún pẹ̀lú òògùn [2]. Díẹ̀ nínú àwọn ènìyàn tún máa ń pe ọ̀nà yìí ní ìdásílẹ̀ ara ẹni, ìṣàkóso ìṣẹ́yún fún ara ẹni, tàbí ìṣẹ́yún tí ẹniyan fúnra rẹ̀ ṣe (DIY).
Nígbà tí o bá lo àwọn òògùn ìṣẹ́yún, ìwọ yóò ní irírí ìṣàn ẹ̀jẹ̀ àti ìrora-ìnu. Àwọn àmì wọ̀nyí jọ ti ǹkan oṣù tàbí oyún tí ó wá lẹ̀ (ìṣẹ́yún aláìfọwọ́fà).
Gbólóhùn "àwọn òògùn ìṣẹ́yún" sábà tọ́ka sí lílo mifepristone atí misoprostol tẹ̀le, tàbí nígbà mìíràn, lílo misoprostol nìkan.
Mife & Miso video
Miso Alone Video
ÒÒGÙN FÚN ÌṢẸ́YÚN
Kí Ni Àwọ́n Tàbíléètì Ìṣẹ́yún?
Báwo ni mifepristone ṣe ń ṣiṣẹ́?
-Mifepristone jẹ́ òògùn tí ó má n dènà progesteron, èyí tí ó je hòmónùù tí ó má ń ṣe àtìlẹyìn fún oyún. Láì sí progesteron, oyún náà kò le dàgbà.
-Mifepristone tún má ń jẹ́ kí ẹnu ònà ilé omo rọ (ìsàlẹ ilé ọmọ) èyí ni yíò jẹ́kí misoprostol ṣiṣẹ́ kíkan kíkan.
Mifepristone nìkan kò tó láti ṣẹ́yún, a nílò Misoprostol náà.
-Ní pàtàkì a máá ń lo Mifepristone fún ìṣẹ́yún tàbí oyún bíbàjẹ́, nítorínà lórí àwọn òfin àti àwọn ìhámó ní orílẹ-èdè kọ̀ọ̀kan, ìgbàmíràn o má n ṣòro láti rí
Báwo ni misoprostol ṣe ń ṣiṣẹ́?
-Misoprostol jẹ́ òogùn tí ó máá ń mú kí ilé ọmọ sùn (tàbí kí ó fún pọ̀) èyí sì ma jẹ́kí oyún wálẹ pẹlú inú rírun àti ẹ̀jẹ̀ dídà
-A lè ṣẹ́ ìṣẹ́yún oníṣègùn pẹ̀lú Misoprostol láì lo mifepristone, àmọ́ lílo méjèèjì papọ má ń múnádóko
-Misoprostol ní àwọn ìwúlò ètò ìlera mìíràn yàtọ̀ sí ìṣẹ́yún (fún ìrọbí, ìsun ẹjẹ lẹ́yìn ọmọ bíbí, ọgbẹ́ inú àti bẹ́ẹ bẹ́ẹ lọ) nítorí náà ó ṣeé rí ní àrọ́wọ́tọ́.
Àwọn ìbéèrè tí wọ́n sábà máa ń béèrè lọ́pọ̀ ìgbà
Lílo mifepristone àti misoprostol láti fòpin sí oyún kò ní nípa lórí oyún tí yóò wáyé lọ́jọ́ iwájú tàbí kó fa àbùkù ìbí lọ́jọ́ iwájú. Àwọn oògùn wọ̀nyí máa ń tètè kúrò nínú ara, wọn kì í sì í ní ipa tó máa wà pẹ́ títí lórí agbára ìbímọ tàbí ìlera ìbímọ, oyún tó bá sì tún wáyé lọ́jọ́ iwájú kò ní ṣàdédé rí bẹ́ẹ̀. Tó o bá ń gbèrò láti lóyún padà, o lè ṣe é nígbàkigbà tó o bá ti múra tán.
Àwọn ìròyìn tuntun àti àwọn àròkọ búlọ̀ọ̀gì tuntun
Gba alàyé ní safe2choose
Màa tẹ̀síwájú pẹ̀lú àwọn ìdàgbàsókè tuntun, ìròyìn, àti àlàyé pẹ̀lú safe2choose. Láti àwọn ìlọsíwájú nínú ìlera ìbímọ sí àwọn ìkìlọ̀ pàtàkì àti àwọn ìtàn láti inú àwùjọ wa, Ojú-ìwé Àwọn Àròkọ wa máa ń jẹ́ kí o mọ gbogbo àlàyé tuntun àti ìfaramọ́ pẹ̀lú àlàyé tuntun.
ÌBÁNISỌ̀RỌ̀ ÀTI ÀTÌLẸ́HÌN
Gba àtìlẹ́yìn àti ìmọ̀ràn nípa ìṣẹ́yún
A ń pèsè àlàyé tó dá lórí ẹ̀rí nípa ìṣẹ́yún àìléwu. Ìrànlọ́wọ́ ìmọ̀ràn wa lófẹ́ẹ́ ní ààbò, a sì ń bójú tó ìtọ́jú aṣírí, ó rọrùn, a kì í ṣe ìdáhùn pẹ̀lú ìdájọ́. A ń dúró dè ìfiranṣẹ́ rẹ!

Nípasẹ̀ ẹgbẹ́ safe2choose àti àwọn amòye alátìlẹ́yìn ní carafem, lórí Ìtọ́sọ́nà Ìtọ́jú Ìṣẹ́yún ti 2022 nípasẹ̀ WHO, Àwọn ìmúdójúìwọ̀n Ilé-ìwòsàn 2023 ní Ìlèra Ìbísí nípasẹ̀ Ipas, àti Àwọn Ìtọ́sọ́nà Àfihàn Ilé-ìwòsàn 2024 fún Ìtọ́jú Ìṣẹ́yún nípasẹ̀ NAF.
safe2choose ní àtìlẹ́yìn nípasẹ̀ Ìgbìmọ̀ Ìmọ̀ràn Ìṣègùn tí a ṣẹ̀dá nípasẹ̀ àwọn amòye asíwájú ní aayé ti ìlera ìbálòpọ̀ àti ìbísí àti àwọn ẹ̀tọ́ (SRHR).
carafem pèsè ìtọ́jú ìṣẹ́yún tí ó rọrùn tí ó sì jẹ́ akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ àti ètò ẹbí kí àwọn ènìyàn lè ṣàkóso iye náà kí wọ́n sì kọjá àwọn ọmọ wọn.
Ipas jẹ́ àjọ àgbáyé tí ó gbájú mọ́ fífẹ̀ àfààní sí ìṣẹ́yún aláìléwu àti ìtọ́jú ìdènà ìbímọ.
WHO - Àjọ Ìlera Àgbáyé - jẹ́ ilé-iṣẹ́ àkànṣe Àjọ Ìparapọ̀ Àwọn Orílẹ̀-èdè tí ó jẹ́ ojúṣe fún ìlera gbogbo ènìyàn àgbáyé.
NAF - National Abortion Federation - jẹ́ ẹgbẹ́ akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ ní USA tí ó ń ṣe àtìlẹ́yìn fún ìtọ́jú ìṣẹ́yún tí ó ní ààbò, tó dá lórí ẹ̀rí àti ẹ̀tọ́ ìbímọ.
