Dr Matt Reeves
MD, MPH, FACOG, ni oludari àgbà ti Dupoint Clinic. | USA
Matthew Reeves, MD, MPH, FACOG n ṣiṣẹ gẹ́gẹ́bí olùdarí Àgbà ti ilé ìwòsan DuPont, ilé iṣẹ́ tí o gbajumọ ètò ìtọjú oyún ṣiṣẹ fun aláìsàn ni eyikeyi oṣù tí oyún ọ̀hùn ibajẹ. Wọ́n di ipò pataki ni ilẹ́ ẹ̀kọ́ gíga tí ìlera tí George Washington, ilé ẹ̀kọ́ gíga tí ìlera tí Stanford àti ilé ẹ̀kọ́ ìlera tí gbogbogbò ti John Hopkins Bloomberg, ti Dr. Reeves sí jẹ́ akọ́ṣẹ́mọṣẹ́.
Gẹ́gẹ́bí akekoo gbọye tí ilé ẹ̀kọ́ ìlera tí Havard, Dr. Reeves parí ìmọ eko tí ibùgbé ni ìmọ eko nípa ìlera obìrin ati bíbí omo ní ilẹ̀ ekó ti California ni San Francisco (UCSF). O tún gbeko gbọye pẹlú ìdàpọ̀ ni ìmọ tí ìlera olutirasandi ni UCSF, ti o tele ìdàpọ̀ ni ètò ifeto ṣọmọ bíbí ni ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Pittsburgh.
Gégé bí ikan lara awon ẹgbẹ America college of obstetricians and gynecologist ati ẹgbẹ ifeto ṣọmọ bíbí, Dr. Reeves tí kò pá ríbiríbi ní ìlànà ìmọ ẹkọ rẹ. Àwọn iṣẹ ti o tí ṣé rí ní Oṣiṣẹ onimọ ìlera àgbà fún Womancare Global àti Oludari onimọ ìlera fún National Abortion Federation. Lọwọlọwọ, o kò pá ríbiríbi nínú ẹgbẹ Clinical Affairs committee of the Society of Family Planning ati ẹgbẹ fún Clinical practice Guidelines for Gynecology of the American College of Obstetricians and Gynecologist. Dr. Reeves sí tún kópa gege bi ọmọ ẹgbẹ́ ti a bùn ọlá fún ní ninu ẹgbẹ American College of Obstetricians and Gynecologists ati ti Society of Family Planning.