Ìwọn ìtẹ̀síwájú ọrọ
safe2choose

Àlàyé Ìṣẹ́yún fún orílẹ̀-èdè kọ̀ọ́kan

Àwọn ofin ìṣẹ́yún àti ìráyè yàtọ̀ káàkiri àgbáyé nítorí àṣà, ẹ̀sìn, àti àwọn idi òṣèlú. Díẹ̀ nínú àwọn orílẹ̀-èdè ti gbẹ́sèle ìṣẹ́yún pátápátá, tí àwọn mìíràn gbà láàyè, nígbàgbogbo pẹ̀lu àwọn ofin kan tí ó dá lórí bíì oyún náà ti jinna si.

Infographic displaying abortion access categories: Permitted per Request, Socioeconomics Grounds, Preserve Health, Save the Life, and Prohibited Altogether.

Àwọn òfin iṣẹyun ní agbáyé

Ní ọgbọ̀n ọdún sẹ́yìn, ọgọ́ta [60] orílẹ̀-èdè ló ti mú kó rọrùn láti ṣẹ́yún, wọ́n sì jẹ́ kó rọrùn fún wọn láàárín àkókò kan pàtó, fún àpẹẹrẹ láàárín ọ̀sẹ̀ méjìlá [12] tàbí mẹ́rìnlá [14] tí wọ́n bá ti lóyún. Bótiwùkórí, mérin (4) nínú mẹ́wà (10) àwọn obìńrin ti ọjọ́-orí ìbísí tún wà ní àwọn agbègbè tí ó ní àwọn ofin ìṣẹ́yún tí ó múná. Ní àwọn agbègbè wọ̀nyí, ìṣẹ́yún le wáyé lábẹ́ àwọn ipò kan, bii ti ẹ̀mí obìńrin nàá bá wà nínú ewu tàbí ní àwọn ọ̀ràn ìfipábánilòpọ̀, tàbí wọ́n lè ní ìdìnàmọ pátápátá [1,2,3].

Iṣẹ́ púpọ̀ tún wà láti ṣe lati rìí dájú pé gbogbo ènìyàn ni ẹ̀tọ́ lati ṣe àwọn ìpinnu nípa ara wọn.

ìráyè ìṣẹ́yún ní àgbáyé

oríṣìíríṣìí àwọn okùnfà le ní ipa lórí ìráyè sí ìṣẹ́yún aìléwu àti ní àkókò. safe2choose ṣe ìrànlọ́wọ́ nípa pípèsè àláyé pàtàkì nípa àwọn ofin ìṣẹ́yún àti ìráyè sí ní oríṣìíríṣìí orílẹ̀-èdè

Wíwá àwọn olùséwàdí

Wíwọlé si ìṣẹ́yún tún dá lórí àwọn orísun tí ó wà bi òògùn, ohun èlò, àti àwọn dókítà Akọ́ṣẹ́mọsẹ́. Àwọn òògùn ìṣẹ́yún bii Mifepristone àti Misoprostol ni a mọ̀ sí aìléwu àti tí o ́sì múnádóko àti pé ó wà lórí àtòkọ àwọn òògùn pàtàkì ti Àjọ Àgbáyé ti Ìlera (WHO) (6, 7). Síbẹ̀síbẹ̀, àwọn òògùn wọ̀nyí kò wà níbi gbogbo, èyí jẹ́ kí ò ṣòro láti ní ìṣẹ́yún aìléwu àti ti ìfaradà ní àwọn agbegbè kan (8, 9).

Àwọn ìdènà ofin

Díẹ̀ nínú àwọn orílẹ̀-èdè ni wọ́n ni ofin gẹ́gẹ́bí àkókò ìdádúró dandan tàbí ìgbaniláayè láti ọ̀dọ̀ àwọn òbí tàbí àwọn ọkọ tàbí aya, èyítí ó le fa ìdádúró kí ò sì ní ipa lórí ṣíṣe ìpinnu (5).

Etò Ọrọ̀ Ajé àti ìpèníjà àgbègbè

Àwọn okùnfà ọrọ̀-ajé àti agbègbè, gẹ́gẹ́bí àwọn idíyelé giga àti nilo láti rìn ìrìn-àjò fún ìtọ́jú, tún le jẹ́ kí o nira lati se ìṣẹ́yún.

Àṣà àti ipa ẹ̀sìn

Àwọn ìgbàgbọ́ àṣà àti ẹ̀sìn pẹ̀lú àbùkù tó yí ìṣẹ́yún ká tún le ní ipa lórí ìráyè sí ìṣẹ́yún. Àbùkù le já sí ìdájọ́ tàbí ìyàsọ́tọ̀, ó jẹ́ kí ó ṣòro fún ènìyàn láti sọ̀rọ̀ nípa tàbí ráyè sí àwọn iṣẹ́ ìṣẹ́yún. Díẹ̀ nínú àwọn òṣìṣẹ́ ìlera le tún yàn láti má ṣe ìṣẹ́yún nítorí àwọn ìgbàgbọ́ ti ara ẹni (10).

Kọ́ ẹ̀kọ́ nípa ìṣẹ́yún ní orílẹ̀-èdè rẹ

Ṣàyẹ̀wò àlàyé yìí ti àwọn ofin ìṣẹ́yún àti ìráyè si ní àwọn orílẹ̀-èdè púpọ̀. Ó pẹ̀lú àlàyé lórí bóyá ìṣẹ́yún wà ní ìlànà ofin, àwọn oríṣìí ìṣẹ́yún tí ó wà, àti àwọn àlàyé nípa àwọn òògùn ìṣẹ́yún, pẹ̀lú tí o bá nílò ìwé òògùn ati iye owó. Ìwọ yóò tún wá àlàyé lórí àwọn àjọ agbègbè àti àwọn orísun fún àfikún àtìlẹ́yìn, àwọn ìmọ̀ràn láti yàgò fún ìtànjẹ, àti bíì o ṣe le dé ọ̀dọ̀ ẹgbẹ́ wa fún ìmọ̀ràn làáyè.

Tí orílẹ̀-èdè rẹ kò bá sí nínú àtòkọ, jọ̀wọ́ ṣàbẹ̀wò sí ojú òpó wẹ́ẹ̀bù alábaṣèpọ̀ wa, Bí o ṣe le lo àwọn òògùn ìṣẹ́yún tàbí kàn sí àwọn olùdámọ̀ràn wa nípasẹ̀ ìméèlì ní info@safe2choose.org.

Illustration of a globe with location markers, a gavel, books, a glass of water, and pills, symbolizing global healthcare law and justice.

Latin America ati Caribbean

Ní Latin America ati Caribbean, ọ̀pọlọpọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè ni wọ́n ni ofin ìṣẹ́yún tí ó múná. Láìpẹ́ ọdún sẹ́yìn, díẹ̀ nínú àwọn orílẹ̀-èdè tí ṣe àwọn àyípadà lati gba ààyè díẹ̀ síi sí ìṣẹ́yún. Ìyípadà yíì ti ní ipa nípasẹ̀ ìgbìyànjú “Green Wave” nípasẹ̀ èyítí àwon ènìyàn ti jà fún ẹ̀tọ́ ìbísi. Pèlú àwọn ìyípadà wọ̀nyí, àwọn ìgbàgbọ́ ẹ̀sìn tí ó lágbára àti àwọn ìgbàgbọ́ ìfarapamó tún jẹ́ kí o ṣòro fún àwọn ènìyàn láti ní ìṣẹ́yún ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn agbègbè ti orílẹ̀-èdè naa.

Map of Latin America and the Caribbean showing abortion laws and access info

Argentina

Ìlú Argentina ṣe ofin ìṣẹ́yún lórí ìbéèrè ti oyun ba to ọsẹ merinla 14 ni ọdun 2020 - ìṣẹ́gun ńlá fún ẹgbẹ́ àbò àti àwọn obìńrin ní agbègbè nàá.

Colombia

Ìlú Columbia sọ ìṣẹ́yún títí di ọ̀sẹ̀ kẹrìnlélógún (24) oyún di ofin ní ọdún 2022 tí ń ṣe apẹẹrẹ pàtàkì ní agbegbè nàá.

Mexico

Àwọn ofin ìṣẹ́yún yàtọ̀ ní ìpínlẹ̀, díẹ̀ nínú wọn gba láàyè títí di ọ̀sẹ̀ méjìlá ti oyún. Ilé-ẹjọ́ giga ti sọ ìṣẹ́yún di ofin ní ọdún 2021, bótilẹ̀jẹ́pé ìmúsẹ rẹ̀ kò se déédéé.

Brazil

Orílẹ̀-èdè Brazil ṣe òdiwọ̀n ìṣẹ́yún, wọ́n gba làáyè nìkan lórí àwọn ọ̀ràn ìfipábánilòpọ̀, eewu sí èmí ìyá, tàbí àwọn ìṣòro tó ṣe pàtàkì pẹ̀lú ìdàgbàsókè ọmọ inú oyún.

El Salvador

Orílẹ̀-èdè yii ní ọ̀kan nínú àwọn ofin ìṣẹ́yún tí ó múná jùlọ ní àgbáyé. Wọn kò fàyè gba Ìṣẹ́yún lábẹ́ botiwùkórí, pàápàá nígbàtí ẹ̀mí ìyà bá wà nínú ewu. Àwọn ènìyàn tí ó se ìṣẹ́yún àti àwọn tí ó ṣe ìrànlọ́wọ́ fún wọn le dojúkọ ìdájọ́ ẹ̀wọ̀n

orilẹ-ede ara Dominican

Ní Orílẹ̀-èdè Dominican, ìṣẹ́yún ní ìlòdìsí púpọ̀ àti pé a gbà láàyé nìkan tí ẹ̀mí ìyá bá wà nínú ewu. Síbẹ̀síbẹ̀, àwọn ìjiyàn tí nlọ lọ́wọ́ àti àwọn ìgbìyànjú lati yí àwọn ofin wọ̀nyí padà, pàápàá ní àwọn ọ̀ràn ti ìfipábánilòpọ̀, ìbálòpò ní ìbátan sí ìbátan, tàbí àwọn ìṣòro ọmọ inú oyún.

Àwọn ìtàn gidi láti inú àwùjọ wa

Ṣàwárí àwọn ìtàn àti irírí tó jinlẹ̀ ti àwọn ẹni tó ti gbẹ́kẹ̀lé safe2choose. àwọn Ìjẹ́risí wọ̀nyí fi ìtìlẹ́yìn àti ìtọ́sọ́nà tí a pèsè hàn, tí ń ṣàfihàn ipa tí àwọn iṣẹ́ wa kó..

Women sharing heartfelt testimonials of trust and support from safe2choose

Even though I was still very apprehensive, I decided to trust them and share my despair. To my surprise, I was warmly welcomed by the counselors and received all the guidance I needed.

I reached out here because I was desperate and didn’t know who to turn to. I had been searching on Google and found this wonderful team. Even though I was still very apprehensive, I decided to trust them and share my despair. To my surprise, I was warmly welcomed by the counselors and received all the guidance I needed. I was quickly referred to the appropriate place, where I was also treated with great care, and I was able to have my abortion in about a week. It was a very positive experience, with kind support and without judgment.

Anonymous, Bùràsílì

Age: 40, October 2025

I don’t feel ready to have another baby. They inserted a copper IUD incorrectly, and I got pregnant.


I decided to have an abortion because I don’t feel ready to have another baby. They inserted a copper IUD incorrectly, and I got pregnant. My baby was born six months ago, I had postpartum depression, and it’s still hard to feel like I’m doing things right. I don’t think a new baby deserves all the stress from work, a small child, and a complicated relationship. The baby’s father didn’t want the pregnancy either.
After the abortion, I felt very guilty. I’m still sad about what happened because I tried to take care of myself and this still happened. I didn’t know what to do or where to go because abortion is illegal in my country. I found this page, and they helped me a lot and gave me contacts to make this a safe process, especially because I had the IUD and that complicated things.
If you’re in a similar situation, the best thing is to talk about it and cry as much as you need to let the grief out. I don’t think this is easy for anyone, especially if you’re a first-time mom.
Also, it’s better to be well informed about contraceptive methods and their side effects... I learned that you have to visit several doctors to get different opinions and inform yourself better. The copper IUD was inserted at my public health provider very soon after my C-section and didn’t protect me for even six months, and it caused this situation that I will never forget.

Anonymous, Bolivia

Age: 30, October 2025

In a country where choice is denied, discovering support reaffirmed the belief in personal freedom.

It was amazing to know that even in a country where we are told we have no choice, there are people out there that still believe in a persons right to choose what to do with their life. Keep up the great work!

Anonymous, Kọ́stà Rikà

Age: 29, May 2025

I am very grateful to them. Be sure that they will take good care of you, no matter where you are. You are the one to decide, but you will never be alone.

Fear was the first feeling I had when I found out I was pregnant. But after I contacted safe2choose, they made me feel safe and confident that they would guide me through the process. The process was very private and easy, and the counselors truly gave me the attention I needed. I am very grateful to them. Be sure that they will take good care of you, no matter where you are. You are the one to decide, but you will never be alone.

Anonymous, Mẹ́ksíkò

Age: 28, July 2024

0/0
User questioning herself, face resting on hand, question mark above her head

ÀLÀYÉ NÍ ÀFIKÚN

Àwon ìbéèrè tí wọ́n béèrè nígbàgbogbo lórí ìṣẹ́yún agbáyé

Ìdí táwọn èèyàn fi máa ń fẹ́ ṣẹ́yún yàtọ̀ síra, ó sì máa ń yàtọ̀ síra. Nígbà tí ẹnì kan bá yàn láti ṣẹ́yún, ìpinnu náà sábà máa ń wáyé lẹ́yìn tó ti gbé ọ̀pọ̀ nǹkan yẹ̀ wò dáadáa, títí kan ipò ara ẹni, ìlera, ipò ìṣúnná owó, àti ipò ìdílé.

Níkẹyìn, ohun tí ẹnì kan bá yàn láti ṣe nípa ara rẹ̀ àti ìlera ìbímọ rẹ̀ jẹ́ ọ̀ràn ara ẹni. Ẹnìkọ̀ọ̀kan ló ní ẹ̀tọ́ láti ṣe àwọn ìpinnu tó dára jùlọ fún ìgbésí ayé àti ipò tirẹ̀, ó sì ṣe pàtàkì láti bọ̀wọ̀ fún òmìnira yìí láìṣe ìdájọ́ tàbí lílọ́wọ́ nínú.

Àwọn ohun èlò tí ó wúlò

Báwò ni o se le múra fún ìṣẹ́yún

Láti múrasílẹ̀ dáradára fún ìṣẹ́yún rẹ, ṣàwárí àwọn óju-ewé wọ̀nyí:

Àwọn ìfìwèránṣẹ́ tuntun àti àwọn ìtanijí lórí àwọn ofin ìṣẹ́yún

Ṣàwárí àwọn àpilẹ̀kọ wa fún àlàyé díẹ̀ sii nípa àwọn oríṣìíríṣìí ofin orílẹ̀-èdè

Kàn sí wa.

Má ṣe ṣiyè méjì láti kan sí wa

Tí o bá nílò àlàyé síi tàbí kò rí ohun tí o n wá, má ṣe ṣiyè méjì láti kan sí wa ní ojúlé ìmọ̀ràn wa àti pẹ̀lú àwọn ọ̀nà ìbánisọ̀rọ̀ wa.

Nípa ẹgbẹ́ safe2choose àti àtilẹhìn lati ọ̀dọ̀ àwọn ilé-iṣẹ àti àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n tí ń pèsè àlàyé àti ìmọ̀ tó kójú òṣùwọ̀n.

safe2choose ni atilẹyin nipasẹ Igbimọ Imọran Iṣoogun ti a ṣẹda nipasẹ awọn amoye asiwaju ni aaye ti ilera ibalopọ ati ilera ibisi ati awọn ẹtọ (SRHR).

[1] "The World's Abortion Laws Map." Center for Reproductive Rights, 2023, https://reproductiverights.org/maps/worlds-abortion-laws/. Accessed November 2024.

[2] Ganatra, B. et al. "Global, regional, and subregional classification of abortions by safety, 2010–14: estimates from a Bayesian hierarchical model." The Lancet, 2017, volume 390, issue 10110, 2372-2381, https://www.thelancet.com/journals/lancet/article/PIIS0140-6736(17)31794-4/fulltext. Accessed November 2024.

[3] "Abortion Law: Global Comparisons." Council on Foreign Relations, https://www.cfr.org/article/abortion-law-global-comparisons. Accessed November 2024.

[4] "Abortion care guideline. Chapter 1. Introduction: An enabling environment for comprehensive abortion care." WHO, 2022, https://srhr.org/abortioncare/chapter-1/an-enabling-environment-for-comprehensive-abortion-care/. Accessed November 2024.

[5] De Londras, F. et al. "The impact of mandatory waiting periods on abortion-related outcomes: a synthesis of legal and health evidence." BMC Public Health, 22, 1232, 2022, https://bmcpublichealth.biomedcentral.com/articles/10.1186/s12889-022-13620-z. Accessed November 2024.

[6] Gibson, L. "WHO puts abortifacients on its essential drug list." BMJ, 2005, 331(7508):68, https://www.ncbi.nlm.nih.gov/pmc/articles/PMC558642/. Accessed November 2024.

[7] "World Health Organization Model List of Essential Medicines – 23rd List, 2023." World Health Organization, 2023, https://www.who.int/publications/i/item/WHO-MHP-HPS-EML-2023.02. Accessed November 2024.

[8] "Mifepristone Approved List." Gynuity, 2024, https://gynuity.org/assets/resources/mife_by_country_and_year_en.pdf. Accessed November 2024.

[9] "Global Abortion Policies Database." GAPD, https://abortion-policies.srhr.org/. Accessed November 2024.

[10] Sorhaindo, A.M., Lavelanet, A.F. "Why does abortion stigma matter? A scoping review and hybrid analysis of qualitative evidence illustrating the role of stigma in the quality of abortion care." Soc Sci Med, 2022, 311:115271, https://www.ncbi.nlm.nih.gov/pmc/articles/PMC9577010/. Accessed November 2024.