Kàn sí wa

A dúpẹ́ pé o ya safe2choose

Tí ó bá wù ọ́ láti gba ìrànlọ́wọ́ ti ara rẹ tàbí tí o bá ní ìbéèrè, jọ̀wọ́ fi ìwé-ránsẹ́ sí àwọn olùbánidámọ̀ràn wa ní info@safe2choose.org tàbí kí o kàn sí wọn lórí pè àyè Wọ́n ma dáhùn ìbéèrè rẹ láì fi àkókò ṣòfò.

Ní ẹnu ìgbà yí, o tún lè wo àwọn ìlànà wa lórí ìsẹ́yún pẹ̀lú oògùn àti ìsẹ́yún pẹ̀lú èrò láti mọ̀ si nípa bí o sele àti ibi tí o ti le sẹ́yún láìléwu. A bọ̀wọ̀ fún ìpinnu rẹ àti wípé, a ó ràn ọ́ lọ́wọ́ nínú ìgbésẹ̀ tí o bá gbé.

Jọ̀wọ́ ka àwọn òfin àti ipò wa àti ìpamọ́ ètò ìmúlò wa kí o tó kàn sí ikọ̀ wá.

Tí o kò bá rí ìpè àyè wa sí ní ìsàlẹ̀ owó ọ̀tún ìbòjú ẹ̀rọ rẹ, jọ̀wọ́ rí dájú wípé o lọ ojú ewé míràn tí o fi ń wá ǹkan lórí ẹ̀rọ rẹ (chrome, mozilla, explorer)