ÀTÌLẸ́YÌN ÌSẸ́YÚN TÓ DÁJÚ
Àwọn ọ̀nà lati Gba Àtìlẹ́yín Ìmọ̀ràn
Fún àlàyé ìmọ̀ràn ìṣẹ́yún kúlẹ̀kúlẹ̀ síi, ṣàbẹ̀wò sí ojú ìwé ìmọ̀ràn wa.
Jọ̀wọ́ ka Àwọn ìlànà àti àdéhùn wa àti Ètò Àṣírí ṣaaju kí o tó kan sí ẹgbẹ́ wa.
Ìwírẹ́gbè pẹ̀lú wa
O lè wọlé sí àtìlẹ́yìn ti ara ẹni nípasẹ̀ ìwírẹ́gbè lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ wa. Àwọn olùgbani-nímọ̀ràn wa tí wọ́n kọ́sẹ́ mọsẹ́ lè dáhùn àwọn ìbéèrè rẹ ní àyíká ìkọ̀kò àti tí kò fi ẹ̀sùn kan ni
*Tí o bá ní ìṣ̣òro ní ṣiṣi àpótí ìwírẹ́gbè lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ ní apá ọ̀tún ìsàlẹ̀ iboju rẹ, jọ̀wọ́ gbiyanju ẹ̀rọ aṣawàkíri míìrán (Chrome, Opera, Mozilla, Explorer).
Fi àtẹ̀jíṣẹ́ ìméèlì ránṣẹ́ sí àwọn olùgbani-nímọ̀ràn
Ṣé o fẹ́ láti kọ̀wé? Ìméèlì info@safe2choose.org, ọkan nínú àwọn olùgbani-nímọ̀ràn wa yóò dáhùn láàrín wọn wákàtí mẹ́rìnlélógún (24). A bọ̀wọ̀ fún ìpamọ́ rẹ a sì máa pa gbogbo ìbánisọ̀rọ̀ mọ́ ní ìkọ̀kọ̀.
ìwírẹ́gbè pẹlú bot wa
Tí o bá nílò àtìlẹyìn ní ìta àwọn wákàtí ọfiisi wa, máṣe yọ ara rẹ lẹ́nu! Chatbot wa wa ni 24/7 láti dáhùn àwọn ìbéèrè ìpìlẹ̀, ṣe ìtọsọ́nà fún ọ sí àwọn orísun ìrànlọ́wọ́ lórí ojú opo wẹ́ẹbu wa, àti so ọ́ pọ̀ mọ́ olùgbani-nímọ̀ràn nígbàtí o nilo.
Àwọn ìlànà ìṣẹ́yún wa
O lè ṣàwárí àlàyé ìṣẹ́yún lórí ìkànnì ayélujára wa ní àkókò rẹ. A pèsè àwọn ìlànà tó ṣe kedere, tí ó rọrùn láti tẹ̀lé fún òògùn àti ìṣẹ́yún pẹ̀lú ẹ̀rọ aláfọwọ́yí. Ìtósọ́nà náà tún wà lórí ibi àti bí tí o ti lè wọlé sí ìṣẹ́yún aláìléwu. A bọwọ fun àwọn ìpinnu rẹ àti pé a wà níbí láti ṣe àtìlẹ́yìn fún ọ ní gbogbo ìgbésẹ̀ ọnà re.
ALÁYÈ ÀTI ASÍRÍ
Kàn sí Wa Nípa Àwọn ìbéèrè ìpamọ́ tàbí Àwọn ìfiyèsí
Tí o bá ní ìbéèrè kankan, ìfiyesi, tàbí àwọn ìbéèrè pàtó nípa ìpamọ́ rẹ tàbí bíì a ṣe n ṣàkóso ìmọ̀ràn ara rẹ, jọ̀wọ́ kàn sí wa.
Fí ìméèlì ránṣẹ́ sí wa ní privacy@safe2choose.org. Láti dáàbò bo dáta rẹ, a yóò ṣàyẹ̀wò ìdánimọ̀ rẹ nípa lílo àdírẹ́sì ìméèlì tí o so mọ́ àkọọ́lẹ̀ rẹ kí a tó gbìyànjú ẹ̀bẹ rẹ. Fún àfikún àlàyé, jọ̀wọ́ ṣàyẹ̀wò ètò ìpamọ́ wa.
ÀJỌṢEPỌ̀ ÀTI ÌFOWÓSOWỌ́PÒ
Ṣepọ̀ Pẹ̀lú Wa
Darapọ̀ mọ́ safe2choose kí o sì jẹ́ ọ̀kan lara Nẹ́tíwọ́ọ̀kì Ìtọ́kasí Àgbáyé wa ti àwọn olùpèsè ìṣẹ́yún, tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ láti ṣe àfikún ànfààní sí ìlera ìbálòpọ̀ àti ẹ̀tọ́ ìbímọ fún gbogbo ènìyàn.
Fún àjọṣepọ̀ àti ìfọwọ́sowọ́pọ̀ ìtọ́kasí, tàbí láti ṣàwárí Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ Olùgbani-nímọ̀ràn Ìṣẹ́yún wa:
Kàn sí ẹgbẹ́ àjọṣepọ̀ wa tààrà ní partnerships@safe2choose.org.
Ṣàwárí Ojúewé Àjọṣepọ̀ wa àti Ìkẹ́kọ̀ Ìṣẹ́yún lórí Ayélujára fún àwọn olùpèsè.