Gbígba ànfààní sí Ìṣẹ́yún
Fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú wa láti ṣe àfikún ànfààní sí àwọn iṣẹ́ ìṣẹ́yún aláìléwu àti láti mú ìdàgbàsókè bá àbájáde ìlera ìbímọ kárí ayé.
Ni safe2choose, a jẹ́wọ́ ìlànà wa lati rii dájú pe gbogbo ènìyàn ní ààyè sí àlàyé deede àti àwọn iṣẹ́ ìlera ìbísí áìléwu. Iṣẹ́ wa ni láti pèsè àtìlẹ́yìn ìkọ̀kọ̀, ìyọ́nú, àti ìpamọ́ fún àwọn tí wọ́n ń wá àṣàyàn ìṣẹ́yún aláìléwu, tí ó ń fún àwọn ènìyàn ní agbára láti ṣe àwọn ìpinnu tó dá lórí ìlera àti ìbáyọ wọn.
Nípa ṣíṣe ìfọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú safe2choose, o lè ràn wá lọ́wọ́ láti mú kí iṣẹ́ wa gbòrò sí i kí o sì kópa nínú nẹ́tíwọ́ọ̀kì àgbáyé àwọn alátìlẹ́yìn ìlera ìbímọ tí wọ́n ṣe ìpinnu láti ṣẹ̀dá ayé tí ó ní ààbò, tí ó ní ìlera.

Darapọ̀ mọ́ wa
Darapọ̣̀ mọ́ nẹ́tíwọ̀ọ́kì àgbáyé ti àwọn Olùpèsè Ìṣẹ́yún tí n ṣiṣẹ́ láti rii dájú pé gbogbo ènìyàn ní àgbáyé ní ààyè sí ìlera ibálòpọ̀ àti ìbísí . Láti jẹ́ ọ̀kan lára nẹ́tíwọ́ọ̀kì ìtọ́kasí wa rọrùn. A tẹ́wọ́ gba àwọn olùpèsè ìlera, àwọn ẹgbẹ́ alátìlẹ́yìn, àti àwọn àjọ tí wọ́n pín ìfọwọ́sowọ́pọ̀ wa sí ẹ̀tọ́ ìbímọ àti ìtọ́jú ìṣẹ́yún aláìléwu.
Kàn sí wa ní partnerships@safe2choose.org láti ṣàfihàn ìfẹ́ rẹ láti darapọ̀ mọ́ nẹ́tíwọ̀ọ́kì naa. A máa nifẹ̀ láti gbọ́ láti ọ̀dọ̀ rẹ!

Ẹgbẹ́ wa yóò kàn sí ọ láti ṣe àyẹ̀wò ìbáramu àti jíròrò àwọn ànfàní àjọṣepọ̀.

fowósowópò pẹ̀lú safe2choose láti gbòòrò ààyè sí àwọn iṣẹ́ ilera ibísí ní agbègbè rẹ. "

ÀWỌN AJỌṢEPỌ TÍ O NÍ IPA
safe2choose jé afárá tí o so àgbáyé pẹ̀lú ipa agbègbè, ní pa fifi ààyè sí àwọn iṣẹ́ ìṣẹ́yún àiléwu àti àlàyé ilera ibísí tí o dájú làti fi agbára fún àwọn agbègbè káàkiri àgbáyé.
"Ẹgbẹ́ wa ti àwọn olùgbani-nímọ̀ràn tí wọ́n kọ́ nípa ìṣègùn àti àwọn alátìlẹ́yìn ń pèsè amójùtò, ìtọ́jú àdáni tí ó dá lórí ìbòwò àti àwọn ìṣe ìṣègùn tí ó dára jùlọ, tí ó ń ṣe àtìlẹ́yìn fún àwọn ènìyàn ní gbogbo ìgbésẹ̀."
safe2choose ń lo ìmọ̀ sáyẹ́ǹsì àgbà tí ó gòkè lọ láti fi pèsè ìmọ́ràn tó péye lórí ayélujára nípa ìṣẹ̀yún, pẹ̀lú ìtójú àṣírí, ní àkókò tó yẹ, tó sì bá eni kọọkan mu.
Pẹpẹ wa ń fún ẹni-kọọkan ní agbára pẹ̀lú àwọn ìtọ́sọ́nà ní sísẹ̀-n-tẹ̀lé, àwọn fídíò, àti àwọn irinṣẹ́ ibanisọrọ, tí ń fi ìmọ̀ tó péye fún wọn láti lè se ìpinnu ilera tí ó dá lórí ìmọ̀
A tẹ́wọ́ gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ ànfààní àjọṣepọ̀, tó fi mọ́:
Fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú wa láti ṣe àfikún ànfààní sí àwọn iṣẹ́ ìṣẹ́yún aláìléwu àti láti mú ìdàgbàsókè bá àbájáde ìlera ìbímọ kárí ayé.
Darapọ̀ mọ́ wa láti ṣe agbátẹrú àti láti gbé àwọn ẹ̀tọ́ ilera ibísí ga, láti rii dájú pé gbogbo ènìyàn ní ìráyè sí àwọn àṣàyàn ìṣẹ́yún aìléwu, tí ó tọ́na, tí kò sí gbowó púpọ̀.
Darapọ̀ mọ́ wa láti gbé ẹ̀kọ́ ibalopọ ga àti ìmọ̀ ìlera ibísí nípasẹ̀ ìwádìí, àwọn ìdánilékò, àti àwọn ìpolóngò lórí èrọ ayélujára.
A gba ìfọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú ilé-iṣẹ́ lati mu ìlọsíwájú ba ìlera ibalopọ àti ibísí nípasẹ̀ àwọn ọ̀nà àbáyọ̀ ìmọ̀tuntun, àwọn ìpìlẹ̀ṣẹ̀ ìgbéowósílè, tàbí àwọn ìpolóngò tí o dojúkọ ọ̀nà sí ìṣẹ́yún
ṢÍṢÀKÓSO ÌTỌ́JÚ ÌṢẸ́YÚN
safe2choose ṣètọ̀ nẹ́tíwọ́ọ̀kì àgbáyé ti àwọn olupese tí a fọwọ́ sí ti nfúnni ní ìtọ́jú tí kìí ṣe ìdájọ́, ìtọ́jú ìṣẹ́yún tó péye, láti rii dájú pé àwọn ènìyàn ní agbáyé ní ìráyè sí ìlèra ti ara ẹni tí kò ní ewu àti àtìlẹ́yìn ìlèra ìbísí àti ìbọ̀wọ̀ fún ènìyàn. Nẹ́tíwọ́ọ̀kì wa gbòòrò kọjá Ọgọrin 80 orílẹ̀-èdè, ó sì ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn olùpèsè ìlera, àwọn nẹ́tíwọ́ọ̀kì agbègbè àti àgbáyé, àti àwọn ẹgbẹ́ àjọṣepọ̀, gbogbo wọn ni wọ́n ṣe ìpinnu láti pèsè ìtọ́jú tó dára jùlọ.
Nẹ́tíwọ́ọ̀kì ìtọ́kasí wa so àwọn ènìyàn pọ̀ mọ́ ọríṣìíríṣìí iṣẹ́, pẹ̀lú ànfààní sí àwọn oògùn ìṣẹ́yún àti ìṣẹ́yún inú ilé ìwòsàn, ìdènà ìbímọ, àtìlẹ́yìn òfin, àti ìmọ̀ràn ọkaǹ, láti dáàbó bo ìlera ìbímọ ni ọ̀nà gbogbo.
Díẹ̀ nínú àwọn alábàṣíṣẹ́pọ̀ ìtọ́kasí pàtàkì wa ní:
MSI Reproductive Choices
International Planned Parenthood Federation (IPPF)
Carafem
Women on Web
LÁTI ÀTÌLẸ́YÌN LÓRÍ AYÉLUJÁRA SÍ ÌTỌ́JÚ LÓRÍ ILẸ̀
Àwọn olùgbàní-ní-mọ̀ràn safe2choose n pèsè ìtákùsọrọ àti àtìlẹ́yìn Ìméèlì fún àwọn tí wọ́n ń wá àṣàyàn ìṣẹ́yún aláìléwu. Fún àfikún ìrànlọ́wọ́, wọ́n darí àwọn ènìyàn sí àwọn olùpèsè tí wọ́n fìdí rẹ̀ múlẹ̀ nítòsí lẹ́yìn àyẹ̀wò pẹ̀lú ìbéèrè tó jinlẹ̀. Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú àwọn alábàáṣiṣẹ́pọ̀ lórí ilẹ̀, safe2choose ń rí i dájú pé ènìyàn ri ànfààní sí ìtọ́jú ìṣẹ́yún tó pé ati to múnádóko.
Mímọ àwọn ìpèníjà ti ààbò tí ó níí ṣe pẹ̀lú àwọn iṣẹ́ ìṣẹ́yún, pàápàá jùlọ ní àwọn agbègbè tí o dènà ìṣẹ́yún, a fi gbogbo àlàyé pamọ́ sínú ibi ìpamọ́ tí woń ti dáàbò bo pátápátá láti rí i dájú pé àsírí àti ààbò wà.
A ṣe ìlérí láti ṣètọ́jú tó dára lóri nẹ́tíwọ́ọ̀kì wa nípa àtìlẹ́yìn àwọn olùpèsè pẹ̀lú àwọn ohun èlò ikẹ̀kọ́ orí ayélujára àti ri dájú pé wọn yẹ láti se ìtọ́jú iṣẹyun àti pínpín àlàyé.
Ìlànà Ìtọ́kasí Safe2choose ní ìgbésẹ̀ màrún:
Ìpìlẹ̀ṣẹ̀ Olùmúlò:
Olùmúlò kan fi ìméèlì ránṣẹ́ tàbí bẹ̀rẹ̀ ̀iwírẹ́gbè lórí ojú òpó wẹ́ẹbu. Gbogbo àlàyé tí wọ́n ba se jẹ́ àṣírí àti ìkọ̀kọ̀.
Àyẹ̀wò:
Àwọn olùgbani-nímọ̀ràn máa ṣe àyẹ̀wò pípéye fún olùmúlò náà.
Ìdámọ̀ àwọn àiní:
Àwọn alámọ̀ràn ṣiṣẹ́ pẹ̀lú olùmúlò láti mọ̀ àwọn aìní wọn àti pèsè àtìlẹ́yìn, nígbàgbogbo pẹ̀lú ìtọ́sọ́nà lórí ìṣẹ́yún aìléwu.
Ìtọ́kasí:
Tí o bá pi dandan, àwọn alámọ̀ràn yóò tọ́ka olùmúlò sí àwọn alábàṣiṣépọ̀ tó wà nìlẹ̀ fún àwọn iṣẹ́ bii òógùn, ìtọ́jú ní ilé-ìwòs̀an, tàbí ìránlọ́wọ́ míìràn.
Ìtọ́jú àti Àtìlẹ́yìn:
Àwọn alábàṣiṣépọ̀ safe2choose n fi inú rere gba àwọn olùmulo tí a tọ́ka sí wọn, láti rii dájú pé wọn gba gbogbo àlàyé pàtàkì, àti láti pèsè ìtọ́jú to dára jùlọ.

ÀWỌN ÀNFÀNÍ ÀJỌṢEPỌ̀
Àwọn ànfàní pàtàkì tó wà nínú dí darapọ̀ mọ́ nẹ́tíwọ́ọ̀kì wa
Jẹ́ apakan nẹ́tíwọ́ọ̀kì ìtọ́kasí wa tí a gbẹ́kẹ̀lé, sopọ̀ pẹ̀lú ẹgbẹẹgbẹ̀rún ènìyaǹ tí n wa ìtọ́jú ilera ìbálòpò ati ibísí nípasẹ̀ àwọn ìtọ́kasí tàárà.
Darapọ̀ mọ́ nẹ́tíwọ́ọ̀kì agbáyé ti ndàgbà tí àwọn olùpèsè ìtọ́jú ìṣẹ́yún láti pàarọ̀ àwọn oye, pín àwọn iṣẹ́ tí o dára jùlọ, àti kópa nínú àwọn ànfàní ìkẹ́kọ̀ agbára.
Gba ìráyè ọ̀fẹ́ si ìkẹ̀kọ̀ orí ayélujára tí o dojúkọ àwọn ìlànà iṣé ìṣẹ́yún àiléwu àti àwọn ọgbọ́n ìmọ̀ràn.
Gba alàyé, ẹ̀kọ́ àti ìbánisọ̀rọ̀ (IEC) ní ọ̀fé láti ṣe àtìlẹ́yìn àwọn ohun èlò rẹ.
Kó pa nínú àwọn àkànṣe agbáyé láti dojúkọ ẹ̀gàn àti dínkù àwọn ìdíwọ́ sí ìlera ibísí.
KÍKỌ́ ÀWỌN Ọ̀NÀ PAPỌ̀
"O nílò àlàyé kedere tí o ṣe àtìlẹ́yìn fún àwọn ènìyàn pẹ̀lú àwọn àṣàyàn ibísí wọn - àti dátà látí MSI àti safe2choose fihàn pé ińtánẹ́ẹ̀tì ṣe ìrànlọ́wọ́ fún ìyẹn - nítorínàa a n ṣe àjọṣepọ̀ látí rii dájú pé àwọn tí o wọlé sí safe2choose le gba ìtọ́kasí ìṣẹ́yún aìléwu tó dára àti àwọn iṣẹ́ ìtọ́jú lẹ́hìn ìṣẹ́yún pẹ̀lú MSI, níbikíbi tí o bá ṣeéṣe."
Ka àpilẹ̀kọ ni ẹ̀kúnrẹ́rẹ́"Láti ìbẹ̀rẹ̀ rẹ̀ ní ọdún 2021, àjọ̀ṣepọ̀ safe2choose pẹ̀lú IPPF ti forúkọ àwọn olùpèsè Ẹgbẹ̀rún mẹ́ta 300 sílẹ̀ láti àwọn ẹgbẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ IPPF ní àwọn orílẹ̀-èdè meje ní Africa ati Asia.Ní ọdún méjì àkọ́kọ́, safe2choose tọ́ka sí àwọn oníbàárà tó lé ní ẹgbẹ̀rún mẹ́ta ó lé ọgọ́rùn-ún mẹ́fà (3,600) sí àwọn ohun èlò IPPF, níbi tí wọ́n ti gba ìtọ́jú ìṣẹ́yún tó dára. Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ yìí ti mú kí ètò ìtọ́jú ìṣẹ́yún pọ̀ sí i, ríi dájú pé ìtọ́jú tó péye tí kò sì ní ìdíwọ́ fún àwọn obìnrin."
Ka àpilẹ̀kọ ni ẹ̀kúnrẹ́rẹ́Àwọn obìnrin lórí ẹ̀rọ ayélujára àti safe2choose ti gbìmọ̀ pọ̀ láti gbé ìmọ̀ nípa iràyé tí ó ṣe é gbẹ́kẹ̀lé lórí ìṣẹ́yún aláìléwu lórí ẹ̀rọ ayélujára nípasẹ̀ ìpolongo náà "Dúró ní ìlera, Wà ní ìmọ̀ nígbà tí o bá ń gba òògùn ìṣẹ́yún." Ìgbésẹ̀ yìí ń pèsè àkójọpọ̀ àwọn ohun èlò, ìmọ̀ràn, àti àwọn ohun èlò lórí ààbò àti ìkọ̀kọ̀ rẹ nígbà tí o bá ń ṣàyẹ̀wò ẹ̀rọ ayélujára, ìtọ́sọ́nà lórí gbígba òògùn ìṣẹ́yún, àti àwọn ìmọ̀ràn lati yàgò fún ẹ̀tàn ni ọ̀dọ̀ àwọn tó ń ta òògùn ìṣẹ́yún tí kò ní ààbò. Àwọn àjọ méjèèjì yìí ṣe ìfilọ́lẹ̀ ní ọdún 2022 ojú ìwé kan láti kó èsì àwọn aṣàmúlò jọ lórí àwọn olùpèsè ìṣẹ́yún èké tàbí àwọn tó ń ta òògùn olóró.
Wo fídíòDarapọ̀ mọ́ nẹ́tíwọ́ọ̀kì ìtọ́kasí wa lónìí láti fọwọ́sowọ́pọ̀ nínú ṣíṣẹ̀dá ayé níbi tí gbogbo ènìyàn ti ní ànfààní sí ìtọ́jú ìṣẹ́yún tí ó ní ààbò, ọ̀wọ̀, àti ẹ̀rí