Àwọn ohun ìrànwọ́ oyún ṣíṣẹ́ – Àwọn ìlànà tí o nílò!

A máa ń pèsè àwọn ohun ìrànwọ́ tí ó wúlò gan-an tí yóò sì ràn ọ́ lọ́wọ́ nígbà tí o bá fẹ́ sẹ́yún. Àlàyé yìí wà ní oríṣiríṣi èdè láti lè ran àwọn obìnrin lọ́wọ́ káàkiri àgbáyé. Má ṣe lọ́ra láti fi sọwọ́ sí àwọn tí o bá lérò pé wọ́n máa nílò rẹ̀. Tí o bá ń fẹ́ àlàyé síwájú sí i, ó lè kàn sí àwọn olùdáninímọ̀ràn wa.

download-resource-img

Àwọn ìlànà ìṣẹ́yún lọ́nà tí kò béwu dé tí o lè gbà lórí ẹ̀rọ ayélujára

Àwọn ìlànà ìṣẹ́yún wa tí ó jẹ́ pdf máa jẹ́ kí o lè gbà á láti orí ẹ̀rọ ayélujára kí o sì lè lò ó níbikíbi, kódà níbi tí kò ti sí àǹfààní láti lo ẹ̀rọ ayélujára.

Oyún ṣíṣẹ́ pẹ̀lú òògùn


download pdf icon Oyún ṣíṣẹ́ pẹ̀lú Mifepristone àti Misoprostol – ENG


download pdf icon Oyún ṣíṣẹ́ pẹ̀lú Misoprostol nìkan – ENG

Oyún ṣíṣẹ́ pẹ̀lú fífà oyún jáde


download pdf icon Oyún ṣíṣẹ́ pẹ̀lú fífà oyún jáde – ENG

video icon

Wo fídíò wa lórí oyún ṣíṣẹ́ lọ́nà tí kò béwu dé

Ó máa ń rọrùn láti mọ ohun tí ó wà nínú fídíò nígbà tí o bá fẹ́ mọ ohun tí ó yẹ kí o retí nígbà tí o bá ń ṣẹ́yún. Wo àwọn fídíò tí ó ń bọ̀ yìí láti mọ̀ nípa àwọn ìlànà oyún ṣíṣẹ́ tí kò béwu dé.

Oyún ṣíṣẹ́ pẹ̀lú fífà oyún jáde

research icon

Ìwádìí

Ìwádìí lórí fífi àbùkù kan àwọn olùtọ́jú oyún ṣíṣẹ́, pẹ̀lú Ipas

safe2choose ṣe ìwádìí káàkiri àgbáyé nípa fífi àbùkù kan àwọn olùtọ́jú oyún ṣíṣẹ́, wọ́n sì ṣe ìjábọ̀ tí ó kún ní àjọṣepọ̀ pẹ̀lú Ipas. Láti ká ohun àbájáde ìwádìí náà, wo ìjábọ̀ wa ní ìsàlẹ̀.

download Results of The International Survey Of Abortion Providers And Companions PDF File - safe2choose & Ipas Ìjábọ̀ tí ó kún – ENG

download International Survey Of Abortion Providers And Companions PDF file - safe2choose & Ipas Ìjábọ̀ ṣókí – ENG

Get prepared for your abortion