Mọ̀ kí o lè baà lè yan ìlànà tí kò béwu dé.

Alaye Iṣẹyun Alailewu

Ṣé ò ń wá àlàyé nípa àti ìlànà oyún ṣíṣẹ́ tí kò béwu dé ní safe2choose? Àwọn ìrírí àwọn èèyàn, òfin tí ó wà fún ìlú kọ̀ọ̀kan, àwọn búlọ́ọ̀gì àti àwọn ohun ìrànwọ́ mìíràn lè ràn ọ́ lọ́wọ́ láti yan ìlànà rẹ.

earth icon

Àwọn ohun ìrànwọ́

A fẹ́ kí ó rọrùn fún ọ láti rí àlàyé nípa oyún ṣíṣẹ́. A ti ṣe àkójọpọ̀ àwọn ìlànà oyún ṣíṣẹ́ tí o lè gbà lórí ẹ̀rọ ayélujára (pdf), àwọn fídíò atọ́nisọ́nà, àti àbájáde ìwádìí wa sí orí àpèrè yìí.

GBA ÀWỌN OHUN ÌRÀNWỌ́


earth icon

Àlàyé nípa oyún ṣíṣẹ́ ní orílẹ̀ èdè kọ̀ọ̀kan

Àǹfààní láti ṣẹ́ oyún àti láti gba ìtọ́jú yàtọ̀ gédégbé láti orílẹ̀ èdè kan sí ìkejì. Láti mọ ohun tí ààyè gbà ní orílẹ̀ èdè rẹ, wo abala àwọn orílẹ̀ èdè.

MỌ̀ NÍPA ORÍLẸ̀ ÈDÈ RẸ


abortion stories icon

Ìrírí níbi oyún ṣíṣẹ́

Ìrírí oníkálukú máa ń yàtọ̀ síra wọn. Gbogbo ìrírí ni ó sì lágbára. Oyún ṣíṣẹ́ jẹ́ kárí ayé, tí a bá sì sọ ìrírí wa, a ó fún àwọn obìnrin mìíràn láti ṣe bẹ́ẹ̀. A lè sọ oyún ṣíṣẹ́ di ohun tí kò ṣe bàbàrà láwùjọ. Ka ìrírí àwọn obìnrin orílẹ̀ èdè rẹ̀ nípa oyún ṣíṣẹ́ kí o ba à lè mọ̀ síi nípa oyún ṣíṣẹ́.

KA ÀWỌN ÌRÍRÍ DÍẸ̀

No Blogs to show