Tani wá àti wípé kíni ìdí tí a fi jẹ́ agbẹnusọ ìṣẹ́yún àìléwu

safe2choose jẹ́ okoòwò fún ìdàgbàsókè àwùjọ tí ó wà lára àjọ àgbáyé fún ìlera àwọn (reproductive health) àti iraye sí ìṣẹ́yún

safe2choose jẹ́ olùbánimọràn orí afẹ́fẹ́ àti àpèrí alálàyé tí ó ran àwọn obìnrin tí ó wù láti ṣẹ́yún pẹ̀lú ògùn tabi iṣẹ́ abẹ nígbà tí ó bá sì ṣe pàtàkì, wọ́n a máa tọ́ka wọn sí alámọ̀dájú akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ èlé tó ìwòsàn nípa ètò ìṣẹ́yún

Àwọn olùbánidàmọ̀ràn gbédè gbẹyọ dókítà àti àwọn akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ nípa ìlera àwùjọ àti àwọn akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ nípa ìlera àwùjọ àti ìdàgbàsókè àgbáyé tí ó péye nípa ìṣẹ́yún aláìléwu ni àwọn tí ó wà lára ikọ̀wa

Kí ni safe2choose le ṣe fún ẹ ?

safe2choose ń pè ṣe àlàyé onímò sáyẹ́ǹsì àti ìmọ̀ràn nípa ìkọ̀wé ránsẹ́ àti ìtakúrọsọ̀ààyè lórí ìṣẹ́yún alàìléwu àti ìṣẹ́yún òníṣé abẹ

Oríṣiríṣi ìlànà ìṣẹ́yún tí kò léwu ló wà
Ní safe2choose a jẹ́ alámọ̀jà nínú pínpín àlàyé nípa ìṣẹ́yún tàbí olóògùn àti ti ẹ̀rọ aláfọwọ́yí fún oyún ọ̀sẹ̀ mẹ̀talá àkọ́kọ́.

Fún àwọn obìnrin tí wọ́n nílò ògùn ìṣẹ́yún òníṣé abẹ, àwọn olùbánidàmọ̀ràn safe2choose máa tọ́ka sí alámọ̀dájú èlétó ìlera

Tí o bá ní ìbéèrè nípa àwọn iṣẹ́ wa, má ṣe sàfira láti kan sí wa. Inú wa máa dùn láti ràn ọ́ lọ́wọ́

Iṣẹ́ wa:

Láti so àwọn obìnrin lágbàáyé pò mọ́ àlàyé tí ó péye nípa ògùn ìṣẹ́yún, kí wọ́n le ní ìṣẹ́yún alàìléwu níbí, nígbà àti pẹ̀lú ẹni tí ó tẹ́ wọn lọ́rùn.

Ìlérí wa:

  • À ń pèsè àlàyé lórí ẹ̀rí sáyẹ́ǹsì tí ó bá àsìkò lọ nípa ìṣẹ́yún aláìléwu.
  • À ń pèsè ìmọ̀ràn ọ̀fẹ́ tí kò léwu tí ó pamọ́ tí ó rọrùn tí kò sì ní ìdájọ́ tàbí àbùkù.
  • À ń sa ipá wa láti tọ́ka rẹ̀ sí alámọ̀dájú, àgbárí tí ó fọwọ́ sí ìṣẹ́yún nígbàtí o bá nílò rẹ̀
  • A kó ni mọ́ra, a má ń ṣe àtìlẹyìn àti wípé ó rọrùn láti kàn sí wa
  • A bọ̀wọ̀ fún ẹ̀tọ́ re láti yan ìpinnu re nípa ìlera rẹ àti ayé rẹ.