Búlọ́ọ̀gì ìṣẹ́yún ti safe2choose: Ìtọ́sọ́nà rẹ sí Ìléra àti ẹ̀tọ́ Ìbímọ
Nígbà tí a bá dojú kọ oyún tí a kò gbèrò, ṣíṣe àyẹ̀wọ àwọn àṣàyàn oogun ìdènà ìbímọ, tàbí o nílò ìtọ́jú ìṣẹ́yún?
Búlọ̀ọ̀gì wa wà lati fun ọ ni agbara pẹlu gbogbo alaye ati atilẹyin ti o nilo! Wo inú àwọn àpilẹ̀kọ wa tí ó rọrùn láti kà lórí ìṣẹ́yún aláìléwu, ṣàwárí àwọn ojúlówó ìtàn láti ọ̀dọ̀ àwọn ènìyàn bíi tìrẹ, kí o sì gba àwọn Àmọ̀ràn kéékèèké àti ìmọ̀ràn tuntun láti ọ̀dọ̀ àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n lórí àwọn ìlò tí ó dára jùlọ fún àwọn oògùn ìṣẹ́yún, Mifepristone àti Misoprostol. Bóyá o ń wá àwọn ìdáhùn tàbí o kàn nílò díẹ̀ nínú ìtọ́sọ́nà ìṣègùn ìṣẹ́yún, búlọ̀ọ̀gì wa ní ohun gbogbo láti ṣe ìrànlọ́wọ́ fún ọ láti ṣe àwọn àṣàyàn tí o dára jùlọ kí o sì ní ìgboyà lórí ìrìn-àjò rẹ.
Wọ inú àwọn àpilẹ̀kọ tó rọrùn láti kà lórí ìṣẹ́yún aláìléwu, kí o sì gba àwọn Àmọ̀ràn kéékèèké àti ìmọ̀ràn tuntun láti ọ̀dọ̀ àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n.
Aaah! Kò sí èsì fún ìṣàwárí rẹ.
Ó ṣeni láàánú, a kò rí àpilẹ̀kọ tí o béèrè fún. Gbìyànjú ọ̀rọ̀ ìwádìí tuntun tàbí ṣàyẹ̀wò àwọn àbá tó wà nísàlẹ̀. Bóyá àwọn àpilẹ̀kọ lórí àkòrí kan náà yóò wúlò fún ọ.
A mọyì èsì yín a sì tẹ́wọ́ gba èrò yín lórí bí a ṣe lè ṣàtúnṣe àwọn iṣẹ́ wa.
Ṣé ojú-ewé yìí ṣe ìrànlọ́wọ́?
Kàn sí wa.
Má ṣe ṣiyèméjì láti kàn sí wa
Má ṣe ṣiyè méjì láti kàn sí wa. Tí o bá nílò àlàyé síi tàbí o kò rí ohun tí o n wá, má ṣe ṣiyè méjì láti kan sí wa ní ojúlé ìmọ̀ràn wa àti àwọn ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ wa.
Gba ìmọ̀ràn ti ara ẹni.
