Ẹkáàbọ̀ sí oludari ojú ìwé ìgbà níní imọran nípa ìlera tí safe2choose, ti a dálé láti ọwọ àwọn akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ ni imo ẹtọ Ibalopọ àti Ibisi (SRHR), ti wọn sì ṣe iranwọ fun awọn ẹgbẹ safe2choose nipa ṣiṣẹ ìfòròwánilénuwò atí títè lè ìlànà okeerẹ tí o jẹ́ mọ̀ oyún ṣiṣẹ tí kò lé wú tí a tí kéde lórí ayelujara àti nipasẹ awọn ẹ́gbẹ̀ agbaniniimoran. Awọn ẹgbẹ Olùdarí àgba níní imọran lórí ìlera má n fowosowopo pẹlú awọn ẹgbẹ safe2choose, tí wón sì ṣe iranwọ ti o kún ojú òṣùwọ̀n tí o jẹ́ mo gbigba ní ní ìmọràn tí mú kí ètò ìtọjú tún bọ gbé péli sí.