Nigeria

  • Anonymous, Nigeria

    Mò ń wá ọ̀nà ìṣẹ́yún tí kò léwu. Mo bá kan safe2choose lórí ẹ̀ro ayélujára, mo yẹ àpèrí náà wò mo sì yàn láti bèrè ìbánisọ̀rọ̀ orí afẹ́fẹ́. Mo bẹ̀rẹ̀ ètò náà, èyítí kò léwu nítorí mo tẹ̀lé àwọn ìlànà tí wọ́n ti pèsè. Ẹ̀mẹẹ̀wá ni ikọ̀ náà ń bámisọ̀rọ̀ láti ríi wípé ètò náà

    READ MORE

  • Anonymous, Nigeria

    Òṣìṣẹ́ safe2choọ̀sẹ̀ fanimóra, ó sì lọ́yàyà. Wọ́n tún ní àkọsílẹ̀ mi nítorínà n kò nílò láti tún àlàyé ṣe nígbàtí mo padà lo kò tilè dámilójú bóyá enìkan náà ni mò ń bá jíròrò láti ìbẹ̀rẹ̀ dé òpin ètò náà, àmọ́ ó dàbí pé enìkan náà ni, onítọ̀hún sì ṣe ìrànwọ́ dáradára. Oyún ṣíṣẹ́ náà

    READ MORE

  • Anonymous, Nigeria

    safe2choose rànmílọ́wọ́ nígbàtí nkò ní ìrètí wọ́n sì tó mi sọ́nà láìléwu. Nígbàtí mò ń ṣẹ́yún, ọjọ̀ àkọ́kọ́ kò fẹ́ẹ̀ ṣé faradà àmọ́ lẹ́yìnwá, ó rọrùn, ó sì tùmílára. Lákòtáń ó dára gidi gan. Wọ́n gba ayé mi àti iyì mi

    READ MORE

  • Anonymous, Nigeria

    Ara dẹ̀ mí nítorí àwọn ìfiyèsí tí wọ́n ní àti ìsọ̀rọ̀sí wọn. Pàápàá jùlọ ìfiyèsi tí wọ́n ní lórí àwọn ǹkan tí kò bá mi lára mu. Mo wà nínú ìyọnu mo sì lérò wípé ògùnlọ́gọ̀ ènìyàn le wà nínú ǹkan báyìí nígbàkan tàbí òmíràn. Àmọ́ safe2choose wúlò nígbàtí mò ń gbé ìgbésẹ̀ yìí.

    READ MORE

Mú orílè èdè náà