Nigeria

Anonymous, Age: 23

Mò ń wá ọ̀nà ìṣẹ́yún tí kò léwu. Mo bá kan safe2choose lórí ẹ̀ro ayélujára, mo yẹ àpèrí náà wò mo sì yàn láti bèrè ìbánisọ̀rọ̀ orí afẹ́fẹ́. Mo bẹ̀rẹ̀ ètò náà, èyítí kò léwu nítorí mo tẹ̀lé àwọn ìlànà tí wọ́n ti pèsè. Ẹ̀mẹẹ̀wá ni ikọ̀ náà ń bámisọ̀rọ̀ láti ríi wípé ètò náà lọ geere. Ẹ má ṣe ṣàfira ṣíse iṣẹ́ takuntakun náà safe2choose!

Mú orílè èdè náà