Share your story

Lójojúmọ́, àwọn obìnrin ní àgbàlá ayé má ń pinnu láti yọ oyún wọn. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ obìnrin ló ti lo ògùn ìṣẹ́yún tí kò léwu, tí ètò rẹ̀ sì ní ìfọ̀kànbalẹ̀ nínú ilé wọn.

Ìṣẹ́yún pẹ̀lú ògùn síì wà ní àrọ́wọ́tó rẹ, ó ṣeé lò ní ìkọ̀kọ̀ àti pé ó rọrùn ju àwọn ọ̀nà ìṣẹ́yún míràn lọ.

Tí o bá ṣẹ́yún pẹ̀lú ògùn tàbí o gba ìrànlọ́wọ́ láti ọwọ́ safe2choose, rántí wípé sísọ ìrírí rẹ ṣe kókó gidigidi fún àwọn obìnrin míràn tí ó fé gbó ẹ̀rí tó dájú àti àtìlẹyìn fún ìpinnu wọn.

Ó ràn wọ́n lọ́wọ́ láti mọ̀ wípé ìṣẹ́yún jẹ́ ohun tí ara ẹni, ìrírí oníkálukú sì yàtò. Sísọ ìrírí rẹ máa gba àkókò péréte o sì le ran obìnrin tí ó ń wá àlàyé nípa isé tí àwọn olùbánidámọ̀ràn wa ń ṣe ní safe2choose.

Lo ìṣẹ́jú díẹ̀ láti so ìrírí àti /tàbí èróngbà rẹ. Lápapò, ẹ jẹ́kí á fihan àgbáyé pé oyún ṣíṣẹ́ kò jẹ́ tuntun, ó sì jẹ́ ipa ayé ẹnikẹ́ni. Lo pẹpẹ yìí láti ṣe ìtànkálẹ̀ ọ̀rọ̀ rẹ àti láti jẹ́kí àwọn obìnrin míràn mọ wípé oyún ṣíṣẹ́ jẹ́ ìpìlẹ̀ ìlera tí wọ́n ní ẹ̀tọ́ sí.

O lè kà nípa ìrírí ìṣẹ́yún àwọn orílẹ̀ èdè àgbáyé ní ìhín yìí.

Mú orílè èdè náà:
  • Sọ ìtàn rẹ!

    Sọ bí ìrírí rẹ pẹ̀lú safe2choose ti rí! Ìṣẹ́jú díẹ̀ ni yóò gbà lọ́wọ́ re.

  • Sọ ìrírí rẹ: fi ìrírí rẹ ránsẹ́ ní èyíkéyìí nínú àwọn ọ̀nà yìí (fídíò, fọ́tò, ohùn gbígbà sílè):

  • safe2choose kò ní kéde ìrírí tí kò bójú mu lọ́nàkọnà, yálà èyítí ó takò ètò àwọn oníṣègùn ìsẹ́yún safe2choose tí àjọ àwọn oníṣègùn àti ikọ̀ oníṣègùn wa.

  • This field is for validation purposes and should be left unchanged.